Back to Africa Check

Rárá, Ọ̀gá àgbà African Development Bank kò ṣàtìlẹyìn fún olùdije fún ipò ààrẹ orílẹ̀dè Nàìjíríà.

Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìfiránṣẹ́ lórí Facebook ni ó ń so wípé ààre African Development Bank, Akínwùnmí Adéṣínà, ń sàtìlẹyìn Bọ́lá Tinubu, ọ̀kan lára ó lé ní méjìlá olóṣèlú ní orílẹ̀dè Nàìjíríà tí ó ń gbìyànjú láti bọ́sípò ààre Muhammadu Buhari ní ọdún 2023.

Àwọn àtẹ̀ránṣẹ́ náà, tí ó jáde ní oṣù kẹ́rin ọdún 2022, nípé Adésínà so wípé: “Tí senator Bọ́lá Ahmed Tinubu bá lè mú kí ọrọ̀-ajé ìpínlè Èkó ṣe ipò káàrún ní ilẹ̀ adúláwọ̀ àti ìpínlẹ̀ tí ewu rẹ̀ kéré jùlọ̀ ní orílẹ̀dè Nàìjíríà, ó yẹ kí a mọ ohun tí ó máa ṣe gẹ́gẹ́ bíi ààrẹ orílẹ̀dè Nàìjíríà.”

Tinubu jẹ́ gómínà ìpínlẹ̀ Èkó ní ọdún 1999 sí 2007 tí ó sì jẹ́ olósèlú tí ó gbajúgbajà ní ìpínlẹ̀ náà àti ní ẹgbẹ́ òṣèlú All progressives congress síbẹ̀.

Lẹ́yìn ìpàdé kan pẹ̀lú Buhari ní ọjọ́ kẹẹ̀wá oṣù kínní ọdún 2022, Tinubu fi ìpinu rẹ̀ hàn láti gbé àpótí dupò ààrẹ ní ètò ìdìbò gbogboògbò ní ọdún 2023.

Sùgbọ́n, ǹjẹ́ Adéṣínà, tí ó jẹ́ mínísítà fún ètò ọ̀gbìn ní orílẹ̀dè Nàìjíríà ní ọdún 2011 sí 2015, ṣàtìlẹyìn Tinubu fún ipò ààrẹ?

Adesina_fake

Ọ́fíìsì Adéṣínà bẹnu àtẹ́ lu ọ̀rọ̀ náà

Ọ̀rọ̀ náà kọ́kọ́ káàkiri lórí èrọ ayélujára ní oṣù kínní ọdún 2022, lẹ́yìn tí Tinubu kéde pé òhun fẹ́ díje dupò ààrẹ.

Adéṣínà bẹnu àté lu ọ̀rọ̀ náa nígbà náà loun.

Ìwé ìròyìn Guardian gbé ìròyìn síta ní ọjọ́ kejìlá ọdún 2022 wípé Victor Ọládòkun tí ó jẹ́ olùdámọ̀ràn àgbà lórí ìbáraẹnisọ̀rọ̀ fún Adéṣina, sọ wípé àwọn ọ̀rọ̀ náà “kìí se òtítọ́, ó ni ẹ̀tàn nínú ó sì jẹ́ iṣé àwọn oníjìbìtì.”

Oládòkun sọ wípé Adéṣínà kò ṣàtìlẹyìn fún ẹnikẹ́ni

Irọ́ ni ọ̀rọ̀ yìí Àmóọ̀, àwọn ọmọlẹ́yìn Tinubu tẹ̀síwájú láti tẹ ìròyìn yìí ránṣẹ́ káàkiri lórí Facebook. 

 

Republish our content for free

We believe that everyone needs the facts.

You can republish the text of this article free of charge, both online and in print. However, we ask that you pay attention to these simple guidelines. In a nutshell:

1. Do not include images, as in most cases we do not own the copyright.

2. Please do not edit the article.

3. Make sure you credit "Africa Check" in the byline and don't forget to mention that the article was originally published on africacheck.org.

For publishers: what to do if your post is rated false

A fact-checker has rated your Facebook or Instagram post as “false”, “altered”, “partly false” or “missing context”. This could have serious consequences. What do you do?

Click on our guide for the steps you should follow.

Publishers guide

Africa Check teams up with Facebook

Africa Check is a partner in Meta's third-party fact-checking programme to help stop the spread of false information on social media.

The content we rate as “false” will be downgraded on Facebook and Instagram. This means fewer people will see it.

You can also help identify false information on Facebook. This guide explains how.

Add new comment

Restricted HTML

  • Allowed HTML tags: <a href hreflang> <em> <strong> <cite> <blockquote cite> <code> <ul type> <ol start type> <li> <dl> <dt> <dd> <h2 id> <h3 id> <h4 id> <h5 id> <h6 id>
  • Lines and paragraphs break automatically.
  • Web page addresses and email addresses turn into links automatically.
limit: 600 characters

Want to keep reading our fact-checks?

We will never charge you for verified, reliable information. Help us keep it that way by supporting our work.

Become a newsletter subscriber

Support independent fact-checking in Africa.