Back to Africa Check

Rárá, ilé iṣé Dangote Cement kò dá iye tí ó ń ta sìmẹ́ntì rẹ̀ sí ìdajì iye rè tẹ́lẹ̀

“Ìròyìn ní yàjóyàjo: Sìmẹ́ntì Dangote ti di N2,700 láti ọjọ́ kínní oṣù kẹwa ọdún 2023. Dangote gé iye sìmẹ́ntì láti 5500 sí 2700. Aliko Dangote ti kéde iye sìmẹ́ntì tuntun gẹ́gẹ́ bí ìdajì iye rẹ̀ tẹ́lẹ̀, láti ọjọ kínní oṣù kẹwa, láti N5500 sí N2700,” bẹ́ẹ̀ ni àtẹ̀ránṣẹ́ kan lórí Instagram kà.

Dangote Cement Plc jẹ́ òkan lára àwọn ilé-iṣé ńlá tí ó ń pèsè sìmẹ́ntì ní ilẹ̀ adúláwọ̀, tí olú ilé-iṣé rẹ̀ sì wà ní ìpínlẹ̀ Èkó, ní orílẹ̀dè Nàìjíríà. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ilé-iṣé tí ó wà lábẹ Dangote Group, tí ọlọ́rọ̀, Aliko Dangote dá sílẹ̀.

Àtẹ̀ránṣé ọ̀hún ni ó lé ní ẹ̀ẹ́dẹ́gbèje èèyàn ti nífẹ̀sí tí aadosan ẹ̀ẹ̀yàǹ si tí dásí. 

A sàbápàdé irúfẹ́ àtẹ̀ránṣé yìí lórí Facebook ní ibí, ibí, ibí, àti ibí àti lórí Instagram ní ibí, ibí, ibí, ibí àti ibí. 

Ṣùgbọ́n ṣé Dangote Cement dá iye sìmẹ́ntì rẹ̀ sí ìdajì iye rẹ̀ tẹ́lẹ̀? A ṣèwádìí. 

DangoteCement_False

‘Ìròyìn èké’

Ní oṣù kẹ́jo ọdún 2023, ilé-iṣé ọ̀hún sọ fún àwọ̀n oníròyìn pé iye tí wọn ta sìmẹ́ntì wà láàrín N4,010 sí N4,640. 

Ó sì sàlàyé pe iye àpò sìmẹ́ntì kan lè tó N5,300 tí wọ́n bá fi owó ọkọ̀ kun. 

Dangote Group sọpé iró ni ọ̀rọ̀ tí wọ́n tẹ̀ránṣé lórí àwọn òpó ìkànsíaraẹni òhún, tí aṣojú rẹ̀ Anthony Chiejine sì tọ́ka sí gẹ́gẹ́ bí “Ìròyìn èké”.

 

Republish our content for free

Please complete this form to receive the HTML sharing code.

For publishers: what to do if your post is rated false

A fact-checker has rated your Facebook or Instagram post as “false”, “altered”, “partly false” or “missing context”. This could have serious consequences. What do you do?

Click on our guide for the steps you should follow.

Publishers guide

Africa Check teams up with Facebook

Africa Check is a partner in Meta's third-party fact-checking programme to help stop the spread of false information on social media.

The content we rate as “false” will be downgraded on Facebook and Instagram. This means fewer people will see it.

You can also help identify false information on Facebook. This guide explains how.

Add new comment

Restricted HTML

  • Allowed HTML tags: <a href hreflang> <em> <strong> <cite> <blockquote cite> <code> <ul type> <ol start type> <li> <dl> <dt> <dd> <h2 id> <h3 id> <h4 id> <h5 id> <h6 id>
  • Lines and paragraphs break automatically.
  • Web page addresses and email addresses turn into links automatically.
limit: 600 characters

Want to keep reading our fact-checks?

We will never charge you for verified, reliable information. Help us keep it that way by supporting our work.

Become a newsletter subscriber

Support independent fact-checking in Africa.