INEC nigeria election meta check job alert Yoruba Irọ́ ni ìpolongo ìgbani síṣẹ́ fún ètò ìdìbò 2023 ti àjọ INEC ti orílẹ̀dè Nàìjíríà
bank notes Central Bank of Nigeria naira Yoruba Rárá, ilé ìfowópamọ́ tí ó gajù lórílẹ̀dè Nàìjíríà kò kéde pé wọ́n ti fi ọjọ́ kún ìgbà tí wọn dá láti má gba àwọn èèyàn láàyè láti ná owo àtijó mo.
Bola Tinubu Biafra war Presidential candidate Yoruba Kò sí ẹ̀rí pé olùdíje dupò ààrẹ lórílẹ̀dè Nàìjíríà Bola Tinubu sọpé òhun “pàdánù àwọn ọmọ kílàsì òhun ní ogun abélé ti Biafra”
soursop cancer cure Yoruba Kò sí èrí tó kúnjúwọ̀n tó fihàn pé èso soursop ń wo ààrùn jẹjẹrẹ
Labour Party Peter Obi Beatrice Itubo Yoruba Kò sí èrí wípé olùdíje dupò gómínà lábẹ́ egbẹ́ òṣèlú Labour sọpé òhun yíò ṣiṣẹ́ láti tako Obi olùdíje dupò ààrẹ lábẹ́ egbẹ́ òṣèlú kan náà
All Progressives Congress Labour Party Bola Tinubu Yoruba Olùdíje dupò ààrẹ orílẹ̀dè Nàìjíríà Tinubu ń wo olùfigagbága rẹ̀ Obi lórí amóhùnmáwòrán inú ọkọ̀ òfurufú? Rárá, ìlú mọ̀ọ́ká kan ni ó tẹ àwòrán tí wọ́n ti ṣarúmọjẹ sí ránṣẹ́
Olusegun Obasanjo APC Bola Tinubu Bola Tinubu Yoruba Rárá, ààrẹ orílẹ̀dè Nàìjíríà tẹ́lẹ̀rí Obasanjo kò fọwọ́sí Tinubu, olùdíje lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú tí ó ń ṣèjọba lọ́wọ́ lórílẹ̀dè Nàìjíríà fún ipò ààrẹ
Bola Tinubu nigeria election meta check Yoruba Rárá, olùdíje dupò ààrẹ lábẹ́ ẹgbé òṣèlú tí ó ń se ìjọba lọ́wọ́, Bola Tinubu kò sọpé òhun kò díje mọ́
African Action Congress Omoyele Sowore nigeria election Yoruba Kò sí èrí wípé olùdíje dupò ààre lórílẹ̀dè Nàìjíríà Omoyele Sowore sọpé àwọn akẹ́ẹ̀kó unifásitì orílẹ̀dè Nàìjíríà yíò ma gba owó ní sáà kànkan tí òhún bá wọlé