Ibrahim Babangida Olusegun Obasanjo Presidential candidate Yoruba Rárá, ọ̀gágun tí ó jẹ́ olórí orílẹ̀dè Nàìjíríà tẹ́lẹ̀rí Babangida kò tweet pé òhun fọ̣wọ́sí bí Obasanjo ṣe fòntè lu Obi olùdíje fún ipò ààrẹ
All Progressives Congress nigeria election meta check Abdullahi Adamu Yoruba Rárá, Alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC tí ó wà lóri àléfà lọ́wọ́ ní orílẹ̀dè Nàìjíríà kò sọpé àjọ tí ó ń rísí èto ìdìbò kò lè fòpin sí bí àwọn tí kò tó dìbò ṣe ń dìbò
APC nigeria election meta check fake quote Yoruba Kò sí ẹ̀rí pé agbẹnusọ ẹgbẹ́ òṣèlú APC tí ó wà lórí àléfà lọ́wọ́ lórílẹ̀dè Nàìjíríà ní èròngbà láti má fàyè gbà kí àwọn ará òkè ọya ó lo ẹ̀rọ ayélujára tàbí rẹ́díò lẹ́yìn ti ààrẹ télẹ̀rí gb
INEC nigeria election meta check job alert Yoruba Irọ́ ni ìpolongo ìgbani síṣẹ́ fún ètò ìdìbò 2023 ti àjọ INEC ti orílẹ̀dè Nàìjíríà
bank notes Central Bank of Nigeria naira Yoruba Rárá, ilé ìfowópamọ́ tí ó gajù lórílẹ̀dè Nàìjíríà kò kéde pé wọ́n ti fi ọjọ́ kún ìgbà tí wọn dá láti má gba àwọn èèyàn láàyè láti ná owo àtijó mo.
Bola Tinubu Biafra war Presidential candidate Yoruba Kò sí ẹ̀rí pé olùdíje dupò ààrẹ lórílẹ̀dè Nàìjíríà Bola Tinubu sọpé òhun “pàdánù àwọn ọmọ kílàsì òhun ní ogun abélé ti Biafra”
soursop cancer cure Yoruba Kò sí èrí tó kúnjúwọ̀n tó fihàn pé èso soursop ń wo ààrùn jẹjẹrẹ
Labour Party Peter Obi Beatrice Itubo Yoruba Kò sí èrí wípé olùdíje dupò gómínà lábẹ́ egbẹ́ òṣèlú Labour sọpé òhun yíò ṣiṣẹ́ láti tako Obi olùdíje dupò ààrẹ lábẹ́ egbẹ́ òṣèlú kan náà
All Progressives Congress Labour Party Bola Tinubu Yoruba Olùdíje dupò ààrẹ orílẹ̀dè Nàìjíríà Tinubu ń wo olùfigagbága rẹ̀ Obi lórí amóhùnmáwòrán inú ọkọ̀ òfurufú? Rárá, ìlú mọ̀ọ́ká kan ni ó tẹ àwòrán tí wọ́n ti ṣarúmọjẹ sí ránṣẹ́