Yoruba Kò sí ẹ̀rí wípé olósèlú ati olùdupò ààrẹ ti orílẹ̀dè Nàìjíríà Bola Tinubu sopé òhun kò ní wá sí ìtàkùrọ̀sọ àwọn olùdupò ààrẹ nítorí àìlera rẹ̀
Yoruba Àwọn ọjọ́ ètò ìdìbò orílẹ̀dè Nàìjíríà ti ọdún 2023 kò yípadà, ó lòdì sí ohun tí wọ́n sọ lóri àwọn òpó ìkànsíaraẹni
Yoruba Ẹ kọtí kún sí ìròyìn èké pé ọlópàá orílẹ̀dè Nàìjíríà tí a dádúró Abba Kyari ti sálọ sí orílẹ̀dè Australia
Yoruba Rárá ilé ìgbìmò aṣòfin ìpínlẹ̀ Èkó kò fi òntẹ̀ lu òfin Sharia láti ran olùdupò ààrẹ orílèdè Nàìjíríà lọ́wọ́
poverty unemployment schools children Peter Obi nigeria election spot check Is Nigerian presidential candidate Peter Obi correct about poverty levels, unemployment and number of children out of school?
Yoruba Ǹjẹ́ àwọn ọmọ orílẹ̀dè Nàìjíríà lè ṣị́ SIM inú fóònù wọn tí wọ́n tìpa láìní nọ́mbà ìdánimọ̀? Rárá, ìtànjẹ ni àtẹ̀ránṣẹ́ yìí
Yoruba Rárá bàlúù kò já lulẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Èkó, Wọn ń gbé bàlúù ti orílẹ̀dè Nàìjíríà kan tí wọ́n tà lọ síbò míràn ni
Liver disease pot belly Yoruba Rárá, yíyọ ikùn ní ìdá àádòrún ìgbà kìí ṣe àmì àìsàn ẹ̀dọ̀- a gbọ́dọ̀ ṣe àyẹ̀wò tó mọ́yán lórí