Yoruba Rárá, ààrẹ orílẹ̀dè Ghana Akufo-Addo kò sọpé kí olùdíje dupò ààrẹ orílẹ̀dè Nàìjíríà Tinubu fààyè gba olùfigagbága rẹ̀ Peter obi
Yoruba Rárá, àjọ immigration ti orílẹ̀dè Nàìjíríà kò gbanisíṣẹ́ lóri Facebook- ọgbọ́n jìbìtì ni
Yoruba Kò sí ẹ̀rí wípé olósèlú ati olùdupò ààrẹ ti orílẹ̀dè Nàìjíríà Bola Tinubu sopé òhun kò ní wá sí ìtàkùrọ̀sọ àwọn olùdupò ààrẹ nítorí àìlera rẹ̀
Yoruba Àwọn ọjọ́ ètò ìdìbò orílẹ̀dè Nàìjíríà ti ọdún 2023 kò yípadà, ó lòdì sí ohun tí wọ́n sọ lóri àwọn òpó ìkànsíaraẹni
Yoruba Ẹ kọtí kún sí ìròyìn èké pé ọlópàá orílẹ̀dè Nàìjíríà tí a dádúró Abba Kyari ti sálọ sí orílẹ̀dè Australia
Yoruba Rárá ilé ìgbìmò aṣòfin ìpínlẹ̀ Èkó kò fi òntẹ̀ lu òfin Sharia láti ran olùdupò ààrẹ orílèdè Nàìjíríà lọ́wọ́
Yoruba Ǹjẹ́ àwọn ọmọ orílẹ̀dè Nàìjíríà lè ṣị́ SIM inú fóònù wọn tí wọ́n tìpa láìní nọ́mbà ìdánimọ̀? Rárá, ìtànjẹ ni àtẹ̀ránṣẹ́ yìí