Yoruba Kò sí ẹ̀rí pé eré ìdárayá ìṣẹ̀jú mẹ́ẹ̀wá yìí lè mú kí pírósítétì tó wú ó súnkì ní kíá kíạ́̀́
Aliko Dangote Yoruba Rárá, ilé iṣé Dangote Cement kò dá iye tí ó ń ta sìmẹ́ntì rẹ̀ sí ìdajì iye rè tẹ́lẹ̀
Yakubu Gowon death death hoax Yoruba Rárá, Olórí ológun tí ó jé adarí orílẹ̀dè Nàìjíríà tẹ́lẹ̀rí, Yakubu Gowon kòì kú
Yoruba Godswill Akpabio impeached senate Rárá, Wọn kò yọ ààrẹ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà ti orílẹ̀dè Nàìjíríà, Godswill Akpabio nípò
Ibrahim Babangida Olusegun Obasanjo Presidential candidate Yoruba Rárá, ọ̀gágun tí ó jẹ́ olórí orílẹ̀dè Nàìjíríà tẹ́lẹ̀rí Babangida kò tweet pé òhun fọ̣wọ́sí bí Obasanjo ṣe fòntè lu Obi olùdíje fún ipò ààrẹ
All Progressives Congress nigeria election meta check Abdullahi Adamu Yoruba Rárá, Alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC tí ó wà lóri àléfà lọ́wọ́ ní orílẹ̀dè Nàìjíríà kò sọpé àjọ tí ó ń rísí èto ìdìbò kò lè fòpin sí bí àwọn tí kò tó dìbò ṣe ń dìbò
APC nigeria election meta check fake quote Yoruba Kò sí ẹ̀rí pé agbẹnusọ ẹgbẹ́ òṣèlú APC tí ó wà lórí àléfà lọ́wọ́ lórílẹ̀dè Nàìjíríà ní èròngbà láti má fàyè gbà kí àwọn ará òkè ọya ó lo ẹ̀rọ ayélujára tàbí rẹ́díò lẹ́yìn ti ààrẹ télẹ̀rí gb
INEC nigeria election meta check job alert Yoruba Irọ́ ni ìpolongo ìgbani síṣẹ́ fún ètò ìdìbò 2023 ti àjọ INEC ti orílẹ̀dè Nàìjíríà
bank notes Central Bank of Nigeria naira Yoruba Rárá, ilé ìfowópamọ́ tí ó gajù lórílẹ̀dè Nàìjíríà kò kéde pé wọ́n ti fi ọjọ́ kún ìgbà tí wọn dá láti má gba àwọn èèyàn láàyè láti ná owo àtijó mo.